Oba Ni Jesu (Live)

Oba Ni Jesu (Live) Lyrics

Oba Ni Jesu (Live)  by EmmaOMG, The OhEmGee Band

Song  ·  21:02  ·  Yoruba

© 2022 OhEmGee Ltd

Oba Ni Jesu (Live) Lyrics

Oba ni Jesu eh
Oba ni Jesu oh oh
Oba ni Jesu ye eh
Oba ni Jesu

Oba ni Jesu (Oba ni o)
Oba ni Jesu (Oba ni o)
Oba ni Jesu (Oba ni o)
Ooh Oba ni Jesu

Mo ti sonu si′nu igbekun ese mi
S'afonifoji iku, ati gbagbe mi
A ti ro mi pin, pe ko si ireti fun mi mo
Tori mo j′ebi, gbogbo esun ta kan mo mi

Mo ti sonu si'nu igbekun ese mi
S'afonifoji iku, ati gbagbe mi
A ti ro mi pin, pe ko si ireti fun mi mo
Tori mo j′ebi, gbogbo esun ta kan mo mi

Sugbon ide mi ja mo d′ominira, lati'gba, mo ti gba Jesu
A ti ra mi pada, a ti san gbese mi, ni pa eje Jesu

Jesus, Yours is the victory (Sing halleluyah o)
Halleluyah, praise the one who sets me free
Halleluyah, death has lost its grip on me
You have broken every chain
There′s salvation in Your name
Jesus Christ, my living hope

Oba ni Jesu eh
Oba ni Jesu oh oh
Oba ni Jesu ye eh
Oba ni Jesu

Oba ni Jesu (Oba ni o)
Oba ni Jesu (Oba ni o)
Oba ni Jesu (Oba ni o)
Ooh Oba ni Jesu

Every situation surrenders to His name
No condition is above His jurisdiction
At the snap of His fingers, everything lost must be restored
Afterall, na only Him be God

I'm walking in power and victory
Tori mo ti mo Jesu
I′m sanctified, I get immunity
Tori moti gba Jesu

Jesus, Yours is the victory (Sing halleluyah o)
Halleluyah, praise the one who sets me free
Halleluyah, death has lost its grip on me
You have broken every chain
There's salvation in Your name
Jesus Christ, my living hope

Say halleluyah

Halleluyah, praise the one who sets me free
Halleluyah, death has lost its grip on me
You have broken every chain
There′s salvation in Your name
Jesus Christ, my living hope

'Cause you have broken every chain
There's salvation in Your name
(Jesus Christ, my living hope)

Tori o ti yo mi kuro ′nu igbekun, o san gbese ese ti mo je
(Jesus, Yours is the victory)

′Cause you have broken every chain
There's salvation in Your name
(Jesus Christ, my living hope)

Oba ni Jesu
Oba ni Jesu
Oba ni Jesu ye eh
Oba ni Jesu

Oba ni Jesu
Oba ni Jesu
Oba ni Jesu
Ooh Oba ni Jesu

Gbogbo aye, gbe Jesu ga
Angel′, e wole fun
Angel', e wole fun
E mu ade Oba Re wa
Se l′Oba, a-a-a-a l'Oba
A-a-a-a l′Oba
A-a-a-a l'Oba
A-a-a-a l'Oba
A-a-a-a l′Oba
A-a-a-a l′Oba
Se l'Oba, awon Oba

Oba ni Jesu
Oba ni Jesu
Oba ni Jesu ye eh
Oba ni Jesu

Oba ni Jesu
Oba ni Jesu
Oba ni Jesu
Ooh Oba ni Jesu

Gbogbo aye, gbe Jesu ga
Angeli, e wole fun
E mu ade Oba Re wa
Se l′Oba, awon Oba

(Gbogbo aye o, yeeeh)

Gbogbo aye, gbe Jesu ga
Angeli, e wole fun
E mu ade Oba Re wa
Se l'Oba, awon Oba

E se l′Oba eyin Martyr
Ti npe ni pepe Re
E ki Eni t'o gba yin la
Se l′Oba awon oba

Gbogbo aye, gbe Jesu ga
Angeli, e wole fun
E mu ade Oba Re wa
Se l'Oba, awon Oba

Oya Oba Oba Oba Oba aye o
Oba ni Jesu (Oba ni o)
Oba ni Jesu (Oba ni o)
Oba ni Jesu (Oba ni o)
Ooh Oba ni Jesu (Oba ni o)

Oba ni Jesu (Oba ni o)
Oba ni Jesu (Oba ni o)
Oba ni Jesu (Oba ni o)
Ooh Oba ni Jesu

Tor'oun ni Arugbo Ojo
Wo, so′pe, eru Oba ni mo ba
Oba to, eru Oba ni mo ba, Oba to
Arugbo Ojo, iwo l′aseda, l'aweda, l′ameda o (Arugbo Ojo)
Iwo loni ogo, loni iyin, loni ola (Arugbo Ojo)
Mo tun wa ni, mo ni
M'ba m′oriki re, m'ba korin lai dake
M′ba fi'jo yin bi okoto Jesu
Ma jo roin roin roin, arugbo (Arugbo Ojo)

Oba, Oba, Oba ni o
Oba ni Jesu (Oba ni o)
Oba ni Jesu (Oba ni o)
Oba ni Jesu (Oba ni o)
Ooh Oba ni Jesu

Oba ni Jesu
Oba ni Jesu
Oba ni Jesu
Ooh Oba ni Jesu

Oya so pe
Mimo, mimo, mimo! Olodumare
Ni kutukutu n'iwo y′o gbo orin wa
Mimo, mimo, mimo! Oniyonu julo
Ologo meta, lae Olubukun

Oba ni, Oba ni, Oba ni o
Oba ni Jesu (Oba ni o)
Oba ni Jesu (Oba ni o)
Oba ni Jesu (Oba ni o)
Ooh Oba ni Jesu (Oba ni o)

Oba ni Jesu (Oba ni o)
Oba ni Jesu (Oba ni o)
Oba ni Jesu (Oba ni o)
Ooh Oba ni Jesu (Oba ni o)

Oba ni Jesu (Oba ni o)
Oba ni Jesu (Oba ni o)
Oba ni Jesu (Oba ni o)
Ooh Oba ni Jesu

Won n′korin kan simi leti, won ni'pe
Si O Olutunu Orun
Fun ore at′agbara Re
A nko, A nko, A nko, Aleluya

Si O, ife eni t'O wa
Ninu Majemu Olorun
A nko, A nko, A nko, Aleluya

Oba ni, Oba ni, Oba ni o
Oba ni Jesu (Oba ni o)
Oba ni Jesu (Oba ni o)
Oba ni Jesu (Oba ni o)
Ooh Oba ni Jesu (Oba ni o)

Oba ni Jesu (Oba ni o)
Oba ni Jesu (Oba ni o)
Oba ni Jesu (Oba ni o)
Ooh Oba ni Jesu

Oba aiku, airi, Orisun Ogbon
To wa n′nu imole, t'oju kole wo
Olubukun julo, Ologo julo
Alagbara, Olu-segun, ′Wo la yin

Oba ni, Oba ni, Oba ni, Oba ni o
Oba ni Jesu
Oba ni Jesu
Oba ni Jesu
Ooh Oba ni Jesu

He is the King, of Kings
He is the Lord, of Lords
His name is Jesus, Jesus, Jesus, Jesus
J-E-S-U-S
He is the King

Oba ni, Oba ni, Oba ni o
Oba ni Jesu (Oba ni o)
Oba ni Jesu (Oba ni o)
Oba ni Jesu (Oba ni o)
Ooh Oba ni Jesu (Oba awon Oba)

Oba ni Jesu (Kabiyesi Re)
Oba ni Jesu (Oba awon Oba)
Oba ni Jesu (Oba awon Oba)
Ooh Oba ni Jesu

Tori ide mi ja mo d'ominira, lati'gba (Mo ti mo Jesu)
Ide mi ja mo d′ominira, lati′gba (Mo ti gba Jesu)

How many of you know Dunsin Oyekan o?

Are you ready?

Dunsin lo soro kan ko ma de fi puro, oso wi pe
Generations, after generations
Keep praising You, yet no word sums you up
Generations, after generations
They keep praising You, yet no word sums up
And I asked the Lord, "What name fits You?
And He said, "Yah", "Yah"

Generations, after generations
They keep praising You, yet no word sums up
And I asked the Lord, "What name fits You?
And He said, "Yah", "Yah"

Yah, the Hallowed One
Jesu Kristi, Yah, the Holy One
Yahweh, the King of Zion

Yah, the Hallowed One
Jesu Kristi, Yah, the Holy One
Yahweh, the King of Zion

Tori boda mi Nathaniel Bassey, ni mo se nso pe, ye-e-e-eh

Hallelujah, Amen
Hallelujah, Amen
Hallelujah, Amen
Sing Hallelujah, Amen

Hallelujah, Amen
Hallelujah, Amen
Hallelujah, Amen
Sing Hallelujah, Amen

Hallelujah, Amen
Hallelujah, Amen
Hallelujah, Amen
Sing Hallelujah, Amen

Mommy, Daddy, wo se Olorun l'aye re o
T′e ba wo'se Olorun l′aye re o
Wa wa ri wipe, wa mo pe, there is nothing He cannot do
There is no mountain He cannot move
There is no prayer He cannot answer
There is no problem He cannot solve
If He has said it, then He will do it
If He has said it, then He will do it
He has a record of keeping His word
He's not about to stop doing it now

Oya sope, Olorun Agbaye, You′re Mighty oh
Olorun Agbal'aye, You're Mighty oh
Shebi wo lo f′oju Orun s′aso bora
Shebi wo le f'oju Orun s′aso bora
Olorun Agbaye, You're Mighty oh

Oba ni Jesu eh eh, Oba ni Jesu
Oba ni Jesu (Oba ni o)
Oba ni Jesu (Oba ni o)
Oba ni Jesu (Oba ni o)
Ooh Oba ni Jesu

Writer(s): Emmanuel Edunjobi<br>Lyrics powered by www.musixmatch.com


More from Oba Ni Jesu (Live)

Loading

You Might Like

Loading


21m 2s  ·  Yoruba

© 2022 OhEmGee Ltd

FAQs for Oba Ni Jesu (Live)